Isaiah 47:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA wí nípa Kalidea pé: “Jókòó kí o dákẹ́ jẹ́ẹ́, kí o sì wọ inú òkùnkùn lọ, ìwọ ọmọbinrin Kalidea. Nítorí a kò ní pè ọ́ ní ayaba àwọn orílẹ̀-èdè mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joko, dakẹ jẹ, lọ sinu okùnkun, iwọ ọmọbinrin ara Kaldea, nitori a ki yio pe ọ ni Iyálode awọn ijọba mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Jókòó ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́, lọ sínú òkùnkùn, ọmọbìnrin àwọn ará Bábílónì; a kì yóò pè ọ́ ní ọbabìnrin àwọn ilẹ̀-ọba mọ́.