Isaiah 47:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O sọ pé ìwọ ni o óo máa jẹ́ ayaba títí lae, nítorí náà o kò kó àwọn nǹkan wọnyi lékàn, o kò sì ranti ìgbẹ̀yìn wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ si wipe, Emi o ma jẹ Iyalode titi lai: bẹ̃ni iwọ kò fi nkan wọnyi si aiya rẹ, bẹ̃ni iwọ kò ranti igbẹhin rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ wí pé, ‘Èmi yóò tẹ̀ṣíwájú títí láé— ọba-bìnrin ayérayé!’ Ṣùgbọ́n ìwọ kò kíyèsí nǹkan wọ̀nyí tàbí kí o ronú nípa ohun tí ó lè ṣẹlẹ̀.