Isaiah 47:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí náà, gbọ́ nisinsinyii, ìwọ tí o fẹ́ràn afẹ́ ayé, tí o jókòó láìléwu, tí ò ń sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Èmi nìkan ni mo wà, kò sí ẹlòmíràn lẹ́yìn mi. N kò ní di opó, bẹ́ẹ̀ ni n kò ní ṣòfò ọmọ.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina gbọ́ eyi, iwọ alafẹ́, ti o joko li ainani, ti o wi li ọkàn rẹ pe, Emi ni, kò si si ẹlomiran lẹhin mi: emi ki yio joko bi opo, bẹ̃ni emi ki yio mọ̀ òfo ọmọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nísinsìn yìí, tẹ́tísílẹ̀, ìwọ oníwọ̀ra ẹ̀dá tí o kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ nínú ààbò rẹ tí o sì ń sọ fún ara rẹ pé, ‘Èmi ni, kò sì sí ẹlòmìíràn lẹ́yìn mi. Èmi kì yóò di opó tàbí kí n pàdánù àwọn ọmọ.’