Isaiah 48:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí mo mọ̀ pé alágídí ni yín, olóríkunkun sì ni yín pẹlu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori emi mọ̀ pe olori-lile ni iwọ, ọrùn rẹ jẹ iṣan irin, iwaju rẹ si jẹ idẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí mo mọ bí ẹ ti jẹ́ olórí kunkun tó; àwọn iṣan ọrùn un yín irin ni wọ́n; iwájúu yín idẹ ni