Isaiah 48:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kò tíì pẹ́ tí a dá wọn, ẹ kò gbọ́ nípa wọn rí, àfi òní. Kí ẹ má baà wí pé: Wò ó, a mọ̀ wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nisisiyi li a dá wọn, ki isi ṣe li atetekọṣe; ani ṣaju ọjọ na ti iwọ kò gbọ́ wọn; ki iwọ má ba wipe, Kiyesi i, emi mọ̀ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A dá wọn ní àkókò yìí kì í ṣe láti ìgbà pípẹ́ ìwọ kò tí ì gbọ́ nípa wọn títí di òní. Nítorí náà, ìwọ kò lè sọ pé, ‘Bẹ́ẹ̀ ni, mo mọ̀ nípa wọn.’