Isaiah 49:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! Òkèèrè ni èyí yóo ti wá, láti àríwá ati láti ìwọ̀ oòrùn, àní láti ilẹ̀ Sinimu.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiye si i, awọn wọnyi yio wá lati ọ̀na jijìn: si wò o, awọn wọnyi lati ariwa wá; ati lati iwọ-õrun wá, ati awọn wọnyi lati ilẹ Sinimu wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsí i, wọn yóò wá láti ọ̀nà jínjìn àwọn díẹ̀ láti àríwá àti àwọn díẹ̀ láti ìwọ̀ oòrùn, àwọn díẹ̀ láti ẹkùn Áṣíwánì.”