Isaiah 49:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Àwọn ọmọ rẹ tí ń pada bọ̀ kíákíá, àwọn olùparun rẹ yóo jáde kúrò ninu rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ rẹ yára; awọn oluparun rẹ ati awọn ti o fi ọ ṣofò yio ti ọdọ rẹ jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ rẹ ti kánjú padà, àti àwọn tí ó sọ ọ́ dahoro ti padà lẹ́yìn rẹ.