Isaiah 49:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó sọ fún mi pé, “Iranṣẹ mi ni ọ́, ìwọ Israẹli, àwọn eniyan óo máa yìn mí lógo nítorí rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wi fun mi pe, Iwọ ni iranṣẹ mi, Israeli, ninu ẹniti a o yìn mi logo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sọ fún mi pé, “Ìránṣẹ́ mi ni ìwọ í ṣe, Ísírẹ́lì nínú ẹni tí n ó ti fi ògo mi hàn.”