Isaiah 5:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn OLUWA àwọn ọmọ ogun ni a óo gbéga ninu ẹ̀tọ́ nítorí ìdájọ́ òdodo Ọlọrun Mímọ́ yóo fi ara rẹ̀ hàn, pé mímọ́ ni òun ninu òdodo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Oluwa awọn ọmọ-ogun li a o gbe ga ni idajọ, ati Ọlọrun Ẹni-Mimọ́ yio jẹ mimọ́ ninu ododo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni a ó gbéga nípa ẹ̀tọ́ rẹ̀, Ọlọ́run ẹni mímọ́ yóò sì fi ara rẹ̀ hàn ní mímọ́ nípa òdodo rẹ̀.