Isaiah 5:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n jẹ́ ọ̀gá ninu ọtí mímu gbé; tí wọ́n jẹ́ akikanju bí ó bá di pé kí á da ọtí líle pọ̀ mọ́ ara wọn!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun awọn ti o ni ipá lati mu ọti-waini, ati awọn ọkunrin alagbara lati ṣe adàlu ọti lile:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ègbé ni fún àwọn akọni nínú wáìnì mímu àti àwọn akíkanjú nínú àdàlú ọtí,