Isaiah 5:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọn ń dá ẹni tí ó jẹ̀bi sílẹ̀ nígbà tí wọ́n bá ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tán; tí wọn kì í jẹ́ kí aláìṣẹ̀ rí ẹ̀tọ́ gbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ẹniti o da are fun ẹni-buburu nitori ère, ti nwọn si mu ododo olododo kuro li ọwọ́ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
tí wọ́n dá ẹlẹ́bi sílẹ̀ nítorí àbẹ̀tẹ́lẹ̀, tí wọn sì du aláre ní ẹ̀tọ́.