Isaiah 5:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ta àsíá, ó fi pe orílẹ̀-èdè kan tí ó wà ní òkèèrè; ó sì fọn fèrè sí i láti òpin ayé. Wò ó! Àwọn eniyan orílẹ̀-èdè náà ń bọ̀ kíákíá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si gbe ọpágun soke si awọn orilẹ-ède ti o jìna, yio si kọ si wọn lati opin ilẹ wá, si kiyesi i, nwọn o yara wá kánkán.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó gbé ọ̀págun ṣókè sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ó jìnnà-réré, Ó súfèé sí àwọn tí ó wà ní ìpẹ̀kun ilẹ̀. Àwọn rè é, wọ́n ti sáré