Isaiah 5:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọfà wọn mú wọ́n kẹ́ ọrun wọn. Pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin wọn le bí òkúta akọ; ẹsẹ̀ kẹ̀kẹ́ ogun wọn dàbí ìjì líle.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ẹniti ọfà wọn mu, ti gbogbo ọrun wọn si kàn, a o ka patakò ẹsẹ ẹṣin wọn si okuta akọ, ati kẹkẹ́ wọn bi ãja.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọfà wọn múná, gbogbo ọrun wọn sì lò; pátakò àwọn ẹṣin wọn le bí òkúta-akọ àwọn àgbá kẹ̀kẹ̀ wọn sì dàbí ìjì líle.