Isaiah 5:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bíbú wọn dàbí ti kinniun, wọn a bú ramúramù bí ọmọ kinniun, wọn a kígbe, wọn a sì ki ohun ọdẹ wọn mọ́lẹ̀, wọn a gbé e lọ, láìsí ẹni tí ó lè gbà á lọ́wọ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kike wọn yio dabi ti kiniun, nwọn o ma ke bi awọn ọmọ kiniun, nitõtọ nwọn o ma ke, nwọn o si di ohun ọdẹ na mu, nwọn a si gbe e lọ li ailewu, kò si ẹnikan ti yio gbà a.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bíbú wọn dàbí tí kìnnìhún, wọ́n bú bí ẹgbọ̀rọ̀ kìnnìhún, wọ́n ń kọ bí wọ́n ti di ẹranànjẹ wọn mú tí wọn sì gbé e lọ láìsí ẹni tí yóò gbà á là.
Recommended Reading