Isaiah 5:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ègbé ni fún àwọn tí ó ń kọ́lé mọ́lé, tí wọn ń gba ilẹ̀ kún ilẹ̀, títí tí kò fi sí ilẹ̀ mọ́, kí ẹ̀yin nìkan baà lè máa gbé ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun awọn ti o ni ile kún ile, ti nfi oko kún oko, titi ãyè kò fi si mọ, ki nwọn bà le nikan wà li ãrin ilẹ aiye!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ègbé ni fún àwọn tí ń kọ́lé mọ́lé tí ó sì ń ra ilẹ̀ mọ́lẹ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ààyè kò ṣẹ́kù tí ó sì nìkan gbé lórí ilẹ̀.