Isaiah 50:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA Ọlọrun ń ràn mí lọ́wọ́, nítorí náà ojú kò tì mí; nítorí náà mo múra gírí, mo jẹ́ kí ojú mi le koko, mo sì mọ̀ pé ojú kò ní tì mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Oluwa Jehofa yio ràn mi lọwọ: nitorina emi kì yio dãmu; nitorina ni mo ṣe gbe oju mi ró bi okuta lile, emi si mọ̀ pe oju kì yio tì mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ràn mí lọ́wọ́; A kì yóò dójú tìmí. Nítorí náà ni mo ṣe gbé ojú mi ró bí Òkúta akọ èmi sì mọ pé, ojú kò ní tì mí.