Isaiah 50:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! OLUWA Ọlọrun ń ràn mí lọ́wọ́, ta ni yóo dá mi lẹ́bi? Gbogbo wọn ni yóo gbọ̀n dànù bí aṣọ, kòkòrò yóo sì jẹ wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiye si i, Oluwa Jehofa yio ràn mi lọwọ, tani o dá mi li ẹbi? wò o, gbogbo wọn o di ogbó bi ẹwù; kokòro yio jẹ wọn run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni ó ń ràn mí lọ́wọ́. Ta ni ẹni náà tí yóò dámí lẹ́bi? Gbogbo wọn yóò gbó bí aṣọ; kòkòrò ni yóò sì mú wọn jẹ.