Isaiah 51:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àbí ìwọ kọ́ ni o mú kí omi òkun gbẹ, omi inú ọ̀gbun ńlá; tí o sọ ilẹ̀ òkun di ọ̀nà, kí àwọn tí o rà pada lè kọjá?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ kọ́ ha gbẹ okun, omi ibu nla wọnni? ti o ti sọ ibú okun di ọ̀na fun awọn ẹni ìrapada lati gbà kọja?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ kọ́ ni ó gbẹ omi òkun bí àti àwọn omi inú ọ̀gbun, Tí o sì ṣe ọ̀nà nínú ìṣàlẹ̀ òkun tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ẹni ìràpadà yóò fi le là á kọjá?