Isaiah 51:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí èmi ni OLUWA, Ọlọrun rẹ, ẹni tí ó rú òkun sókè, tí ìgbì rẹ̀ fi ń pariwo; OLUWA àwọn ọmọ ogun ni orúkọ mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi Oluwa Ọlọrun rẹ ti o pin okun ni iyà, eyi ti ìgbi rẹ̀ nhó; Oluwa awọn ọmọ-ogun ni orukọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run rẹ, tí ó ń ru òkun ṣókè tó bẹ́ẹ̀ tí ìgbì rẹ̀ fi ń pariwo OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀.