Isaiah 51:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kò sí ẹni tí yóo tọ́ ọ sọ́nà, ninu gbogbo àwọn ọmọ tí o ti bí, kò sí ẹni tí yóo fà ọ́ lọ́wọ́, ninu gbogbo ọmọ tí o tọ́ dàgbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kò si ẹnikan ninu gbogbo awọn ọmọ ọkunrin ti o bí lati tọ́ ọ; bẹ̃ni kò si ẹniti o fà a lọwọ, ninu gbogbo awọn ọmọ ọkunrin ti on tọ́ dàgba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú gbogbo ọmọ tí ó bí kò sí ọ̀kankan tí ó lè tọ́ ọ sọ́nà nínú gbogbo ọmọ tí ó tọ́ kò sí èyí tí ó le fà á lọ́wọ́.