Isaiah 52:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹnu ti ya ọpọlọpọ eniyan nítorí rẹ̀. Wọ́n bà á lójú jẹ́ yánnayànna, tóbẹ́ẹ̀ tí ìrísí rẹ̀ kò fi jọ ti eniyan mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi ẹnu rẹ ti yà ọ̀pọlọpọ enia, a bà oju rẹ̀ jẹ ju ti ẹnikẹni lọ, ati irisi rẹ̀ ju ti ọmọ enia lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí a ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n ń bọlá fún un— ìwò ojú rẹ ni a ti bà jẹ́ kọjá ti ẹnìkẹ́ni àti ìrísí rẹ̀ ní a ti bàjẹ́ kọjá ohun tí ènìyàn ń fẹ́