Isaiah 52:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lákọ̀ọ́kọ́, àwọn eniyan mi lọ ṣe àtìpó ní ilẹ̀ Ijipti, lẹ́yìn náà, àwọn ará Asiria pọ́n wọn lójú láì nídìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori bayi li Oluwa Jehofa wi, Awọn enia mi sọkalẹ lọ si Egipti li atijọ lati ṣe atipo nibẹ; ara Assiria si ni wọn lara lainidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí èyí ni ohun tí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí. “Ní ìgbà àkọ́kọ́ àwọn ènìyàn mi ṣọ̀kalẹ̀ lọ sí Éjíbítì láti gbé; láìpẹ́ ni Áṣíríà pọ́n wọn lójú.