Isaiah 52:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbọ́, àwọn aṣọ́de rẹ gbóhùn sókè, gbogbo wọn jọ ń kọrin ayọ̀, nítorí wọ́n jọ fi ojú ara wọn rí i, tí OLUWA pada dé sí Sioni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn alóre rẹ yio gbe ohùn soke; nwọn o jumọ fi ohùn kọrin: nitori nwọn o ri li ojukoju, nigbati Oluwa ba mu Sioni pada.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tẹ́tísílẹ̀! Àwọn olùṣọ́ rẹ gbé ohùn wọn ṣókè wọ́n kígbe papọ̀ fún ayọ̀. Nígbà tí OLÚWA padà sí Ṣíhónì, wọn yóò rí i pẹ̀lú ojúu wọn.