Isaiah 54:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ẹnìkan bá dojú ìjà kọ ọ́, kìí ṣe èmi ni mo rán an, ẹnikẹ́ni tó bá gbéjà kò ọ́, yóo ṣubú nítorí rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiye si i, ni kikojọ nwọn o kó ara wọn jọ, ṣugbọn ki iṣe nipasẹ mi; ẹnikẹni ti o ba ditẹ si ọ yio ṣubu nitori rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ẹnikẹ́ni bá tilẹ̀ bá ọ jà, kò ní jẹ́ láti ọwọ́ọ̀ mi; ẹnikẹ́ni tí ó bá bá ọ jà ni yóò túúbá fún ọ.