Isaiah 54:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí o óo tàn kálẹ̀, sí apá ọ̀tún ati apá òsì, àwọn ọmọ rẹ yóo gba ìtẹ́ àwọn orílẹ̀-èdè, wọn óo sì máa gbé àwọn ìlú tí ó ti di ahoro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori iwọ o ya si apa ọtún ati si apa osì, iru-ọmọ rẹ yio si jogun awọn keferi: nwọn o si mu ki awọn ilu ahoro wọnni di ibi gbigbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìwọ ó fẹ̀ sọ́tùn-ún àti sí òsì; ìrandíran rẹ yóò jogún àwọn orílẹ̀ èdè, wọn yóò sì dó sí ahoro àwọn ìlú wọn.