Isaiah 56:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí OLUWA ní, “Bí ìwẹ̀fà kan bá pa ọjọ́ ìsinmi mi mọ́, tí ó bá ṣe ohun tí mo fẹ́, tí ó sì di majẹmu mi mú gbọningbọnin,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori bayi li Oluwa wi fun awọn ìwẹfa ti nwọn pa ọjọ isimi mi mọ, ti nwọn si yàn eyi ti o wù mi, ti nwọn si di majẹmu mi mu;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé ohun tí OLÚWA wí nìyìí: “Sí àwọn ìwẹ̀fà yìí tí ó pa ọjọ́ ìsinmi mi mọ́, tí wọ́n yan ohun tí ó dùn mọ́ mi tí wọ́n sì di májẹ̀mú mi mú ṣinṣin