Isaiah 56:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA Ọlọrun tí ń kó àwọn tí ogun túká ní Israẹli jọ sọ pé, “N óo tún kó àwọn mìíràn jọ, kún àwọn tí mo ti kọ́ kó jọ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa Jehofah, ẹniti o ṣà àtanu Israeli jọ wipe, Emi o ṣà awọn ẹlomiran jọ sọdọ rẹ̀, pẹlu awọn ti a ti ṣà jọ sọdọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA àwọn ọmọ-ogun sọ wí pé— ẹni tí ó kó àwọn àtìpó Ísírẹ́lì jọ: “Èmi yóò kó àwọn mìíràn jọ pẹ̀lúu wọn yàtọ̀ sí àwọn tí a ti kó jọ.”