Isaiah 56:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè láti òkèèrè, ẹ máa bọ̀, gbogbo yín ẹ máa bọ̀ bí ẹranko inú ìgbẹ́, ẹ wá jẹ àjẹrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo ẹnyin ẹranko igbẹ, ẹ wá lati pajẹ ani gbogbo ẹranko igbẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin ẹranko inú un pápá, ẹ wá jẹ àwọn ẹranko inú igbó run!