Isaiah 57:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí ń rìn ní ọ̀nà òtítọ́, wọn óo wà ní alaafia, wọn óo máa sinmi lórí ibùsùn wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On wọ̀ inu alafia: nwọn simi lori akete wọn, olukuluku ẹniti nrin ninu iduroṣinṣin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn tí ń rìn déédéé ń wọ inú àlàáfíà; wọ́n rí ìsinmi bí wọ́n ti ń sùn lókùú.