Isaiah 57:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yin ọmọ oṣó wọnyi, ẹ súnmọ́bí fún ìdájọ́, ẹ̀yin ọmọ alágbèrè ati panṣaga.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹ sunmọ ihin, ẹnyin ọmọ oṣo, iru-ọmọ panṣaga on àgbere.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ṣùgbọ́n ìwọ wá níhìnín, ìwọ ọmọ àjẹ́ yìí, ìwọ ìran panṣágà àti aṣẹ́wó!