Isaiah 57:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ẹ̀yin tí ẹ kún fún ìṣekúṣe lábẹ́ igi Oaku, ati lábẹ́ gbogbo igi eléwé tútù. Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń pa àwọn ọmọ yín láàrin àfonífojì, ati ní abẹ́ àpáta?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti òriṣa ngùn labẹ gbogbo igi tutù, ti ẹ npa awọn ọmọ wẹrẹ ninu afonifoji wọnni, labẹ apáta ti o yanu?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ gbinájẹ fún ìṣekúṣe láàrin igi óákù àti lábẹ́ gbogbo igi tí ń gbilẹ̀; ẹ fi àwọn ọmọ yín rúbọ nínú kòtò jínjìn àti lábẹ́ àwọn pàlàpálá òkúta.