Isaiah 59:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí àìdára wa pọ̀ níwájú rẹ, ẹ̀ṣẹ̀ wa sì ń jẹ́rìí lòdì sí wa; nítorí àwọn àìdára wa wà pẹlu wa, a sì mọ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori irekọja wa npọ̀ si i niwaju rẹ, ẹ̀ṣẹ wa njẹri gbè wa, nitori irekọja wa mbẹ lọdọ wa, niti aiṣedede wa, awa mọ̀ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwọn àṣìṣe wa pọ̀ níwájú rẹ, àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa sì ń jẹ́rìí takò wá. Àwọn àìṣedéédéé wa sì wà pẹ̀lú wa, àwa pẹ̀lú sì mọ àìṣedéédéé wa,