Isaiah 59:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “N óo wá sí Sioni bí Olùràpadà, n óo wá sọ́dọ̀ àwọn ọmọ Jakọbu, tí wọ́n yipada kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olurapada yio si wá si Sioni, ati sọdọ awọn ti o yipada kuro ninu irekọja ni Jakobu, ni Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Olùdáǹdè yóò wá sí Ṣíhónì, sí àwọn tí ó wà ní Jákọ́bù tí ó ronúpìwàdá ẹ̀ṣẹ̀ wọn,” ni OLÚWA wí.