Isaiah 59:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀ ń bá paramọ́lẹ̀ pa ẹyin rẹ̀, ẹ sì ń ran òwú aláǹtakùn, ẹni tí ó bá jẹ ninu ẹyin yín yóo kú. Bí ẹnìkan bá fọ́ ọ̀kan ninu ẹyin yín, ejò paramọ́lẹ̀ ni yóo jáde sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn npa ẹyin pamọlẹ, nwọn nhun okùn alantakùn: ẹniti o jẹ ninu ẹyin wọn yio kú, ati eyi ti a tẹ̀ bẹ́ ọká jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń pa ẹyín pamọ́lẹ̀ wọn sì ń ta owú aláǹtakùn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ẹyin wọn yóò kú, àti nígbà tí a pa ọ̀kan, pamọ́lẹ̀ ni ó jáde.