Isaiah 59:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ kò mọ ọ̀nà alaafia, kò sí ìdájọ́ òdodo ní ọ̀nà yín. Ẹ ti mú kí ọ̀nà yín wọ́, ẹni tó bá ba yín rìn kò ní ní alaafia.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọ̀na alafia ni nwọn kò mọ̀; kò si idajọ kan ninu ìrin wọn: nwọn ṣe ipa-ọ̀na wiwọ́ fun ara wọn: ẹnikẹni ti o ba tọ̀ ọ kì yio mọ̀ alafia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀nà àlàáfíà èyí ni wọn kò mọ̀; kò sí òdodo ní ojú ọ̀nà wọn wọ́n ti sọ wọ́n dì ọ̀nà kọ́rọkọ́rọ, kò sí ẹni tí ó tọ ọ̀nà yìí tí yóò rí àlàáfíà.