Isaiah 62:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn orílẹ̀-èdè yóo rí ìdáláre rẹ, gbogbo ọba ni yóo rí ògo rẹ; orúkọ tuntun, tí OLUWA fúnra rẹ̀ yóo sọ ọ́, ni a óo máa pè ọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn Keferi yio ri ododo rẹ, ati gbogbo ọba yio ri ogo rẹ: a o si fi orukọ titun pè ọ, eyiti ẹnu Oluwa yio darukọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn orílẹ̀ èdè yóò rí òdodo rẹ, àti gbogbo ọba ògo rẹ a ó sì máa pè ọ́ ní orúkọ mìíràn èyí tí ẹnu OLÚWA yóò fi fún un.