Isaiah 63:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn wọ́n hùwà ọlọ̀tẹ̀: wọ́n sì mú Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ bínú. Nítorí náà ó di ọ̀tá wọn, ó sì dojú ìjà kọ wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nwọn ṣọ̀tẹ, nwọn si bi Ẹmi mimọ́ rẹ̀ ninu; nitorina li o ṣe pada di ọta wọn, on tikalarẹ̀ si ba wọn ja.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ wọ́n sì ba Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ nínú jẹ́. Bẹ́ẹ̀ ni ó yípadà ó sì di ọ̀ta wọn òun tìkálára rẹ̀ sì bá wọn jà.