Isaiah 63:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹni tí ó gbé agbára rẹ̀ tí ó lógo wọ Mose, tí ó pín òkun níyà níwájú wọn, kí orúkọ rẹ̀ lè lókìkí títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti o fi ọwọ́ ọtun Mose dà wọn, pẹlu apá rẹ̀ ti o logo, ti o npin omi meji niwaju wọn, lati ṣe orukọ aiyeraiye fun ara rẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ta ni ó rán ògo apá ti agbára rẹ̀ láti wà ní apá ọ̀tún Mósè, ta ni ó pín omi níyà níwájú wọn, láti gba òkìkí ayérayé fún ara rẹ̀,