Isaiah 63:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó mú wọn la ibú omi kọjá, bí ẹṣin ninu aṣálẹ̀; wọ́n rìn, wọn kò fẹsẹ̀ kọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti o mu wọn là ibú ja, bi ẹṣin li aginjù, ki nwọn ki o má ba kọsẹ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ta ni ó ṣíwájú wọn la àwọn ọ̀gbun nì já? Gẹ́gẹ́ bí ẹṣin ni gbangba ìlú wọn tí kò sì kọṣẹ̀;