Isaiah 63:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n rìn wọnú àfonífojì bíi mààlúù, Ẹ̀mí OLUWA sì fún wọn ní ìsinmi. Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe darí àwọn eniyan rẹ̀, kí ó lè gba ògo fún orúkọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi ẹran ti isọ̀kalẹ lọ si afonifoji, bẹ̃ni Ẹmi Oluwa mu u simi: bẹ̃ni iwọ tọ́ awọn enia rẹ, lati ṣe orukọ ti o li ogo fun ara rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran tí ó lọ sí pápá oko, a fún wọn ní ìsinmi láti ọwọ́ Ẹ̀mí OLÚWA. Báyìí ni ẹ ṣe tọ́ àwọn ènìyàn yín láti fún ara yín ní orúkọ kan tí ó lógo.