Isaiah 63:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo fi ibinu tẹ àwọn orílẹ̀-èdè mọ́lẹ̀, mo fi ìrúnú rọ wọ́n yó, mo sì tú ẹ̀jẹ̀ wọn dà sílẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi si tẹ̀ awọn enia mọlẹ ninu ibinu mi, mo si mu wọn mu yó ninu irunú mi, mo si mu ipa wọn sọkalẹ si ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo tẹ orílẹ̀ èdè mọ́lẹ̀ nínú ìbínú mi; nínú ìrunú mi mo jẹ́ kí wọ́n mu mo sì da ẹ̀jẹ̀ wọn sílẹ̀ lórí erùpẹ̀.”