Isaiah 63:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní, “Dájúdájú eniyan mi mà ni wọ́n, àwọn ọmọ tí kò ní hùwà àgàbàgebè.” Ó sì di Olùgbàlà wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si wipe, Lõtọ enia mi ni nwọn, awọn ọmọ ti kì iṣeke: on si di Olugbala wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wí pé, “Lótítọ́ ènìyàn mi ni wọ́n, àwọn ọmọ tí kì yóò jẹ́ òpùrọ́ fún mi”; bẹ́ẹ̀ ni, ó sì di Olùgbàlà wọn.