Isaiah 64:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ti dáná sun ilé mímọ́ wa tí ó lẹ́wà, níbi tí àwọn baba wa ti yìn ọ́, gbogbo ibi dáradára tí a ní, ló ti di ahoro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ile wa mimọ́ ati ologo, nibiti awọn baba wa ti nyìn ọ, li a fi iná kun: gbogbo ohun ãyo wa si ti run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tẹ́ḿpìlì Mímọ́ ológo wa, níbi tí àwọn baba wa ti yìn ọ́, ni a ti fi iná sun, àti ohun gbogbo tí í ṣe ìṣúra wa ti dahoro.