Isaiah 64:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA, ṣé o kò ní ṣe nǹkankan sí ọ̀rọ̀ yìí ni? Ṣé o óo dákẹ́, o óo máa fìyà jẹ wá ni?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o ha da ara rẹ duro nitori nkan wọnyi, Oluwa? iwọ o ha dakẹ, ki o si pọn wa loju kọja àla?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn gbogbo nǹkan wọ̀nyí, OLÚWA, ìwọ ó ha sì tún fara rẹ pamọ́ bí? Ìwọ ó ha dákẹ́ kí o sì fìyà jẹwá kọjá ààlà bí?