Isaiah 64:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
bí ìgbà tí iná ń jó igbó ṣúúrú, tí iná sì ń mú kí omi hó. Kí orúkọ rẹ di mímọ̀ fún àwọn ọ̀tá rẹ, kí àwọn orílẹ̀-èdè lè máa gbọ̀n níwájú rẹ!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi igbati iná ileru ti njo, bi iná ti imu omi hó, lati sọ orukọ rẹ di mimọ̀ fun awọn ọta rẹ, ki awọn orilẹ-ède ki o le warìri niwaju rẹ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí iná mú ẹ̀ka igi jó tí ó sì mú kí omi ó hó, ṣọ̀kalẹ̀ wá kí orúkọ rẹ le di mímọ̀ fún àwọn ọ̀ta rẹ kí o sì jẹ́ kí àwọn orílẹ̀ èdè kí ó wárìrì níwájú rẹ!