Isaiah 64:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò sí ẹnìkan tí ń gbadura ní orúkọ rẹ, kò sí ẹni tí ń ta ṣàṣà láti dìmọ́ ọ; nítorí pé o ti fojú pamọ́ fún wa, o sì ti pa wá tì nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kò si ẹniti npè orukọ rẹ, ti o si rú ara rẹ̀ soke lati di ọ mu: nitori iwọ ti pa oju rẹ mọ kuro lara wa, iwọ si ti run wa, nitori aiṣedede wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnikẹ́ni kò pe orúkọ rẹ tàbí kí ó gbìyànjú láti dì ẹ́ mú; nítorí ìwọ ti fi ojú rẹ pamọ́ fún wa ó sì jẹ́ kí àwa ṣòfò dànù nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.