Isaiah 64:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sibẹsibẹ OLUWA, ìwọ ni baba wa, amọ̀ ni wá, ìwọ sì ni amọ̀kòkò; iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nisisiyi, Oluwa, iwọ ni baba wa; awa ni amọ̀, iwọ si ni ọ̀mọ; gbogbo wa si ni iṣẹ ọwọ́ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀, OLÚWA, ìwọ ni Baba wa. Àwa ni amọ̀, ìwọ ni ọ̀mọ; gbogbo wa jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.