Isaiah 65:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ilé Ṣaroni yóo di ibùjẹ ẹran, àfonífojì Akori yóo sì di ibi tí àwọn ẹran ọ̀sìn yóo máa dùbúlẹ̀ sí, fún àwọn eniyan mi, tí wọ́n wá mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣaroni yio di agbo-ẹran, ati afonifoji Akori ibikan fun awọn ọwọ́ ẹran lati dubulẹ ninu rẹ̀, nitori awọn enia mi ti o ti wá mi kiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣárónì yóò di pápá oko fún ọ̀wọ́ ẹran, àti àfonífojì Ákò yóò di ibi ìsinmi fún agbo ẹran, fún àwọn ènìyàn mi tí ó wá mi.