Isaiah 65:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn iranṣẹ mi yóo máa kọrin nítorí inú wọn dùn, ṣugbọn ẹ̀yin óo máa kígbe oró àtọkànwá; ẹ óo sì máa sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, nítorí àròkàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, awọn iranṣẹ mi yio kọrin fun inudidun, ṣugbọn ẹnyin o ke fun ibanujẹ ọkàn, ẹnyin o si hu fun irobinujẹ ọkàn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìránṣẹ́ mi yóò kọrin láti inú ayọ̀ ọkàn wọn wá, ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò kígbe sókè láti inú ìrora ọkàn yín àti ìpohùnréré ní ìròbìnújẹ́ ọkàn.