Isaiah 65:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Orúkọ tí ẹ óo fi sílẹ̀ fún àwọn àyànfẹ́ mi yóo di ohun tí wọn yóo máa fi gégùn-ún. Èmi Oluwa Ọlọrun óo pa yín. Ṣugbọn n óo pe àwọn iranṣẹ mi ní orúkọ mìíràn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin o si fi orukọ nyin silẹ fun egún fun awọn ayanfẹ mi: nitori Oluwa Jehofah yio pa ọ, yio si pè awọn iranṣẹ rẹ̀ li orukọ miran:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin yóò fi orúkọ yín sílẹ̀ fún àwọn àyànfẹ́ mi gẹ́gẹ́ bí ègún; OLÚWA àwọn ọmọ-ogun yóò sì pa yín, ṣùgbọ́n fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ni òun yóò fún ní orúkọ mìíràn